Àjàní Akéwì Concept
@ajaniakewi
ÀJÀNÍ AKÉWÌ CONCEPT; Literary critic, Yorùbá enthusiast, Prestigious Yorùbá chanter and On Air Personality.
ID: 1513596306027073542
https://www.youtube.com/@ajaniakewiconcept 11-04-2022 19:14:42
160 Tweet
94 Followers
125 Following
Ọ̀gbẹ́ni Ayo of Ibadan sọ pé àwọn yóó fún ẹni tí ó bá mọ àdúgbò yìí ní Ìbàdàn ní ẹ̀bùn tó jọjú 🏃🏃🏃🥰🥰🥰 📷: Ayo Adams
MISS IBADAN AWARD PAGEANT 2024 Miss Ibadan and Awards Dr. Aderonke Omo Dairo
Inú mi dùn láti jẹ ọ̀kan lára àwọn tí yóó àǹfààní ètò ÌDÁNILẸ́KỌ̀Ọ́ ọlọ́ṣẹ̀ méjì lórí bí a ti ń pèdè pegedé tí Ọ̀gbẹ́ni ArugboBoisi àti àwọn ikọ̀ yókù ṣe àgbékalẹ̀ rẹ. Elédùà áá máa wà pẹ̀lú yín, a dúpẹ́ púpọ̀!
Inú mi dùn láti jẹ ọ̀kan lára àwọn Akéwì tí ó kópa nínú ÌDÍJE ORÍKÌ ÌWÓ tí ó wáyé ní ààfin ọba Olúwòó tí ilẹ̀ ÌWÓ... Láìfọ̀rọ̀gùn, Àjàní Akéwì láti Ọ̀yọ́ Aláàfin jáwé olúborí gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó ṣe ipò kínní láàrin àwọn olùkópa yókù. Alhamdulilah! Iwoland Hub
Today's class was very awesome as we had a number of experienced tutors who shared their insights, knowledge and experience with us. Kudos to ArugboBoisi of JblissMedia and the entire team 🥰🥰🥰
The journey of journalism and documentation continues Reporting live with Ọ̀gbẹ́ni Ayo of Ibadan from Onkola Village, Oyo State. 📷 Ayo Adams
Join me for an unforgettable experience as I perform my prestigious Yorùbá oral literature at not one, but TWO exciting events today : POWER OF TAPS organised by Artsmithonline.nft POWER LINE organized @voidsandvoices Register here 🔗 bit.ly/PowerLines2024 See you there ✨🥰